Home BioGraPhy & History Oriki Ibadan (Eulogy Of Ibadan)

Oriki Ibadan (Eulogy Of Ibadan)

87
0

Oriki Ibadan

The Yoruba people of Western Nigeria are known for their beautiful and amazing customs and traditions of which the art of oriki (eulogy or praise poetry) is among. The people of Ibadan, in particular, have rich history and cultures that make them one of the most popular tribes in Yoruba land and Nigeria. Below is the oriki of Ibadan. Enjoy!

Oriki Ibadan

Ibadan mesi Ogo, nile Oluyole.
Ilu Ogunmola, olodogbo keri loju ogun.
Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya.
Ilu Ajayi, o gbori Efon se filafila.
Ilu Latosa, Aare-ona kakanfo.

Ibadan Omo ajoro sun,
Omo a je Igbin yoo, fi ikarahun fo ri mu.
Ibadan maja-maja bii tojo kin-in-ni,
eyi too ja aladuugbo gbogbo logun,
Ibadan ki ba ni s’ore ai mu ni lo s’ogun.
Ibadan Kure! Ibadan beere ki o too wo o,
Ni bi olè gbe n jare olohun.

B’Ibadan ti n gbonile bee lo n gba Ajoji;
Eleyele lomi ti teru-tomo ‘Layipo n mu,
Asejire lomi abumu-buwe nile Ibadan.
A ki waye ka maa larun kan lara,
Ija igboro larun Ibadan.

Thanks for reading, oldnaija.com

Ibadan kini so? We hope you enjoyed the oriki Ibadan. If yes, kindly drop a comment below. You can also rep your agbole in Ibadan.

Kindly give us credit and backlink. No thief our contents o or else we report you to Google. Questions? Advert? Click here to mail us or click here to call us on 08061389617